Kilódẹ̀ Ti Ó Má Nfọ Ọwo Rẹ̀? - Olubunmi Aboderin Talabi

Kilódẹ̀ Ti Ó Má Nfọ Ọwo Rẹ̀?

By Olubunmi Aboderin Talabi

  • Release Date: 2020-02-10
  • Genre: Children's Fiction

Description

Yoruba

Ọ́wó fífọ dada le dá arún dúró.
.
Ójẹ ọ̀nà tí kó ná ní lówó tí ó sí wú ló púpọ̀ lati sé itọjú ara dádá.

KÍLÓDÉ TI Ó MÁ NFỌ ỌWỌ RẸ?

Jé ọ̀ná ídárá yá láti kọ́ ọmọdé ní pàtàkí ọwọ́ f́ifọ́. Pẹlu àwòrán tí ó jọjú atí èdè tí kó lé, ọmọdé ma fẹ́ látí ka iwé yì atí látí kó awón àwòrán tí ofá ní mó ra lẹyín itán náà jọ.

KÍLÓDÉ TI Ó MÁ NFỌ ỌWỌ RẸ?

dárá fún awón tí ó sẹ̀sẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí mó iwé ká laí nóní ọjọ órí wón, ó sí tún dárá fún igbà alọ. O dárá latí fí sí inú àpò ẹbún fún ajọ yọ ọjọ́ ìbì atí gbogbo ajóyọ tí ẹ fẹ́ se.

Ra iwé yi fún àwon ọmọ tí o yí yín ka atí dí ẹ̀ si latí fún awón mírán.

English

Proper hand washing can prevent the spread of disease. It is an effective and affordable way to practice good hygiene.

Why Do You Wash Your Hands? is a fun way to teach Children the importance of hand washing. With colorful illustrations and simple language, children will love reading this book.

Why Do You Wash Your Hands? is wonderful for early readers of all ages and perfect for story time.

This book deploys a fun pictorial style to help children and their parents understand the importance of regular hand washing whilst learning the different occasions before or after which they should wash their hands.

Why Do You Wash Your Hands? is the first indigenous Nigerian children’s picture book to be published simultaneously in 4 languages – English, Yoruba, Igbo and Hausa.